iBet uBet web content aggregator. Adding the entire web to your favor.
iBet uBet web content aggregator. Adding the entire web to your favor.



Link to original content: https://yo.wikipedia.org/wiki/Lucie_Hradecká
Lucie Hradecká - Wikipedia, ìwé-ìmọ̀ ọ̀fẹ́ Jump to content

Lucie Hradecká

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lucie Hradecká

Lucie Hradecká je agba eyin oju konkere (tenis) O je eniti o ti gbegba oroke Grand slam ni igba meta ototo, Ayo ti french open odun 2011 ati Ayo US open ti awon obinrin pelu akegbe re Andrea Hlavackova ni Odun 2013 ati Ayò ti French Open pelu akegbe re František Čermák ni odun 2013. Hradecká tun de ipele to keyin nibi eyin ori konkere ti Wimbledon Championship ti odun 2012, ipele to keyin ti US open ni odun 2012 ati ipele to keyin ti Australian Open ni odun 2016, ati ipele to keyin ataayo oni mejimeji ti US open ni Odun 2017 ati Australian Open ti odun 2013, ati French Open oni didapo ni odun 2015. Hradecká de oke tente ise re gegebi agbá eyin ori konkere to dara julo pelu ipo kerin lagbaye ni Ojo kerin Osu kewa odun 2012, ti o si ti gbami eye merindinlogbon ti WTA, pelu meta ami eye ohun to gba ni ipele egberun ti WTA, ti o si de ipele to keyin ti WTA Tour Championships ni odun 2012.

Ni Ojukoju, Hradecká ti de ipele ikokanlelogoji gegebi eni to dara julo lagbaye ni osu kefa Odun 2011, ti o si de ipele to keyin Ayo Eyin ori konkere onilusilu meje. Sise daadaa julo re waye nibi ayo Australian Open ti odun 2015, nibiti o ti fidi eni to daa julo lagbaye remi, Ana Ivanovic nibi a tii wo ipele keta ayo naa. Hradecká tun je eni ti o ti gbami eye Olympic seyin, o gba ami eye wura nibi ipele awon obinrin oni meji meji ni Odun 2012 pelu akegbe re Hlaváčková. O gba ami eye ide nibi Ayo oni meji meji ni odun 2016 pelu akegbe re Radek Štepanek. O ti soju orileede Czech Republic nibi idije Billie Jean King Cup lati odun 2010. O je okan gboogi lara awon to se daadaa julo nibi idije naa nibiti o ti gbami eye marun laarin odun 2011 si 2016