Brad Pitt
Ìrísí
Brad Pitt | |
---|---|
Brad Pitt - Hollywood California - July 2019 | |
Ọjọ́ìbí | William Bradley Pitt 18 Oṣù Kejìlá 1963 Shawnee, Oklahoma, U.S. |
Iṣẹ́ | Actor, producer |
Ìgbà iṣẹ́ | 1987–present |
Olólùfẹ́ | Jennifer Aniston (m. 2000; div. 2005) Angelina Jolie (m. 2014) |
Àwọn ọmọ | 6 |
Àwọn olùbátan | Àdàkọ:Plain list |
Brad Pitt jẹ́ òṣèré eré orí ìtàgé àti atọ́kùn eré ọmọ orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà. Ó ti gba ẹ̀bùn akádẹ́mì lẹ́ẹ̀mẹ́ta gẹ́gẹ́ bí olùgbéjáde eré lábẹ́ ilé iṣẹ́rẹ̀, Plan B Entertainment. Pitt kọ̣́kọ́ di mímọ̀ gẹ́gẹ́ bíi darandaran nínú eré Thelma & Louise (1991).[1][2]
Àwọn eré tí ó ti kópa
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Thelma & Louise (1991)
- A River Runs Through It (1992)
- Kalifornia (1993)
- True Romance (1993)
- Interview with the Vampire (1994)
- Legends of the Fall (1994)
- Seven (1994)
- 12 Monkeys (1995)
- Sleepers (1996)
- Seven Years in Tibet (1997)
- Meet Joe Black (1998)
- Fight Club (1999)
- Snatch (2000)
- The Mexican (2001)
- Spy Game (2001)
- Ocean's Eleven (2001)
- Troy (2004)
- Ocean's Twelve (2004)
- Mr. & Mrs. Smith (2005)
- Babel (2006)
- The Assassination of Jesse James by the Coward Robert Ford (2007)
- Ocean's Thirteen (2007)
- The Curious Case of Benjamin Button (2008)
- Inglourious Basterds (2009)
- Tree of Life (2011)
- Moneyball (2011)
- World War Z (2013)
- 12 Years a Slave (2013)
- Fury (2014)
- The Big Short (2015)
- Allied (2016)
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Peyser, Andrea (2010). Celebutards. Citadel Press. p. 81. ISBN 978-0-8065-3384-1. https://books.google.com/?id=mQhjzHbUEyoC&pg=PA81&dq=%22William+Alvin+Pitt%22+trucking+company#v=onepage&q=%22William%20Alvin%20Pitt%22%20trucking%20company&f=false.
- ↑ Bunbury, Stephanie (December 14, 2008). "The business of being Brad". Sydney Morning Herald. http://www.smh.com.au/news/entertainment/film/the-business-of-being-brad/2008/12/13/1228585167094.html.