iBet uBet web content aggregator. Adding the entire web to your favor.
iBet uBet web content aggregator. Adding the entire web to your favor.



Link to original content: https://yo.wikipedia.org/wiki/Ìpínlẹ̀_Ìlàòrùn-Àrin
Ìpínlẹ̀ Ìlàòrùn-Àrin - Wikipedia, ìwé-ìmọ̀ ọ̀fẹ́ Jump to content

Ìpínlẹ̀ Ìlàòrùn-Àrin

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Ipinle East Central je ipinle amojuto tele ni Nigeria. O je dida ni 27 May 1967 lati awon apa Agbegbe Apailaorun o si wa titi di 3 February 1976, nigbati o je pinpin si ipinle meji - Anambra ati Imo. Loni awon ipinle marun ni won wa nibi to wa tele: Anambra, Imo, Enugu, Ebonyi ati Abia. Ilu Enugu ni o je oluilu re nigbana.

Awon Gomina/Olumojuto Ipinle East Central

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]