Tokunbo Afikuyomi
Ìrísí
Tokunbo Afikuyomi je aṣojú-ṣòfin ni Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin orílẹ̀èdè Nàìjíríà lọ́dún 1999 sí ọdún 2003. Tokunbo Afikuyomi jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀èdè Nàìjíríà, tí ó ti fi ìgbà kan rí jẹ́ sẹ́nétọ̀ tí ó ń ṣojú ẹ̀kùn gbùngbùn Èkó ní ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ Ìjọba olómìnira ìkẹrìn lábẹ́ ẹgbẹ́ òsèlú AD (Alliance for Democracy).[1] Ọdún 1999 ni ó gun orí àléfà. Ó pààrọ̀ ẹ̀kùn ní oṣù Igbe ní ọdún 2002 kúrò ní gbùngbùn lọ sí apá àríwá, lẹ́yìn tí Sẹ́nétọ̀ Wahab Dosunmu ṣídìí lọ sí ẹgbẹ́ òṣèlú PDP.
Ìtàn ìgbésí ayé
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Senator Afikuyomi’s Political Wilderness". THISDAYLIVE. 2019-07-28. Retrieved 2023-09-29.