Dabo Aliyu
Dabo Aliyu | |
---|---|
Fáìlì:Portrait of Dabo Aliyu in uniform.jpg | |
Governor of Anambra State | |
In office November 1993 – December 1993 | |
Asíwájú | Chukwuemeka Ezeife |
Arọ́pò | Mike Attah |
Governor of Yobe State | |
In office 14 December 1993 – 14 August 1996 | |
Asíwájú | Bukar Abba Ibrahim |
Arọ́pò | John Ben Kalio |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 29 Oṣù Kejìlá 1947citation needed] Batsari - Kastina State[citation needed] | [
Aláìsí | 13 December 2020 | (ọmọ ọdún 72)
(Àwọn) olólùfẹ́ | Khadija Dabo Aliyu |
Olùrànlọ́wọ́ Ìǹspẹ́kítọ̀ Gbogbogbò ti ọlọ́pàá (fẹ̀hìntì) Dabo Aliyu CON mni psc jẹ́ Alákoso ìjọba ní ìpínlẹ̀ Anambra láti Oṣù kọkànlá sí Oṣù kejìlá ọdún 1993, ó sì ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí àbojútó ìpínlẹ̀ Yobe láti Oṣù kejìlá ọdún 1993 sí Oṣù kẹjọ ọdún 1996 ní àkókò ìjọba ológun ti General Sani Abacha. Ó jẹ́ olùrànlọ́wọ́ Olùdárí NSO State House Annex nígbà kan, ó tún jẹ́ Ìrànlọ́wọ́ Ìǹspẹ́kítọ̀ Gbogbogbò ti ọlọ́pàá ti agbègbè Zone 7 Abuja. A fún un ní àmì-ẹ̀yẹ lórí Ìdènà àwọn ìwà burúkú, ẹ̀bùn lórí Kọmísọ́nà ọlọ́pàá tí ó dára jùlọ nípasẹ̀ Olùyẹ̀wò Gbogbogbò ti ọlọ́pàá àtí ẹ̀bùn lórí iṣẹ́ ọlọ́pàá tó dára jùlọ ní Ìpínlẹ̀ Anambra. Ó ń gbé ní Ìpínlẹ̀ Kaduna, ó jẹ́ Sardaunan Ruma àkọ́lé ní ìlú abínibí rẹ̀, Ruma.[1]
Àwọn Ìtọ́ka Sí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Nigerian States". WorldStatesmen. Retrieved 2010-01-04.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |